Now Reading
Otunba Jingosa – by @MASKURAID

Download Issue #2
FREE
DOWNLOAD NOW

Otunba Jingosa – by @MASKURAID

[color-box]

Please note: the story is in Yoruba language. R18+

[/color-box]

Ara Otunba o bale mo.

 

“Wa Kola, wo bar geh yen, ki lo ri si?”

Kolade siwo oti to fe gbe senu, o yipada wo apa ibi t’Otunba n n’awo si.

“Baba, ri si bii ti ba wo? E la ye mi sir.”

 

Inu fe bi Otunba die sugbon o paa mora.

“Bawo lo se ma n se bayi gan Kola? Mo ni koo ye omo wo, o n so pe ki n la ye e. Iwo je bii baby abi JJC ni? Joo gbe cup owo e sile koo wo smallie yen dada jare. Se o ri pe geh yen set ni?”

“E ma binu Otunba, mi o mo pe nkan te n so niyen. Bhet ki n se spec yin l’omo yi sir? Mo ro pe awon nkan rabata le ma n toka si ni, awon nkan bamba, awon wumandiesel. Eleyi a kan tee ba ko lu o.”

 

Otunba rerin muse.

“Looto lo so Kola. Tele tele, awon eja nla nla milligram ni mo ma n je sugbon mo pade skelewu kan lose to koja ni Laspotech. Ayayaya, pelebe l’omo yen looto sugbon razor ni. Ti mo se n ju l’oun gan n dapada. Ki n to ye gear, oun gan ti te clutch. O gbe mi rin bi motor tuntun l’ori titii marose. O do mi bii pe ko r’okori.”

 

Suraju bu serin keeke.

“Otunba!!!!!! Omoge le ponle bayi? E wo be se n soro nipa obo bii pe o koja keeyan do ko si wo.”

 

“Ha! Suraju! Ma je kan ba e gbo o. O koja bee walahi. Too ba pade omo ti mo n so yi, eru a ba iwo gaan. Ani omo yi do mi anyhow. O mo pe mi o ki n se learner. Ti n ba so pe omo koja bee, o ni lati je confam. Idi ti mo se n wo eleyi naa niyen o, oun ati omo ti mo n r’oyin e yi jo ni shape bakanaa ni. Bi mo se n wo eleyi naa, oun gaan a le gbemi eeyan.”

 

“Ehn Otunba, to ba je beeni e gbe sunmo ngba yen. Abi? Ki lo tun ku? Ojo ta aba r’ibi ni ibi n wole nau.”

 

Kia, Otunba fa telefonu yo lapo, o naa si Suraju.

“Gba ogbeni, lo gba nomba e wa fun mi. O saa mo pe ogboogbon l’agbalagba fi n sa fun maalu. Ma je ki n lo fara mi wole.  Koko gba nomba e wa funmi, emi a pee, maa organize baa se maa rira.

 

Suraju runmu po bi eni pe ko fe dide.

“Ki lo n se bobo yi? Ma so fun mi pe o le gba nomba omo ele fun mi.”

Sibe Suraju o gba telefoonu l’owo Otunba.

“Ehen, se bayen ni? Okay, 5K wa lapo mi fun enikeni to ba mu nomba ati oruko omo yen de bi laarin iseju marun.”

K’Otunba to jale oro, Kolade ti gba foonu n ti e.

“5k abi kin i mo gbo yen? Mo n bo.”

Kia lo dide, lo k’ori sona bar pelu foonu lowo osi. Otunba rerin muse.

“Kare jare Kola ti o kere. Mo jeri e, o o go ra e ri.”

 

Leyin iseju marun, Kolade pada de.

 

“Otunba baba o! Mo ti gbe de o, yakaare! E guess nkan ti mo ba bo.”

“Ki ni, ki lo fe ju nomba ati oruko lo?”

“Oruko ati nomba bawo, emi o ma bayen wa rara.”

 

Ara Otunba ro woo.

 

“Haba, ki wa lo n be kaakiri fun? Se too ba le sise taa ran e, o de ni waste time oluwa e. O ti aga e seyin bii pe o fe dide.  Joo Suraju, je ka lo jare.”

 

“Baba! Se e trust mi mo ni? Emi Kola lo ma n so roo? Mo n m’eye bo lapo e n siye meji boya dudu ni abi pupa. E gbo nkan ti mo fe so no kee to binu nau.”

“O daa na, ki lo ba bo?”

 

“Mo ti ba geh yen soro, Sade l’oruko e. Mo so fun pe baba alaye bambam kan wan nibi to n je dodo e gan, pe baba alaye yen nko jee gaan ni. Mo ni to ba le gbara duro fun baba, walahi baba ma a ba su je le l’ori. Bi mo se mention oro owo bayi, eti e na ni. In fact, mo so fun pe to ba le te baba lorun, baba gaan a make sure pe oun naa o regret. Ki ni mo so bee fun, Sade ba dahun, o ni ki n so fun baba pe ti baba o ba mind o,  ki baba wo toilet awon obinrin to kangun s’ogiri lapa otun yen. Koun sare fun baba ni preview.”

 

“Ooto abi fabu?”

“Fabu bawo Otunba? Oya, eyin e wo toilet kee duro dee. Ti o ba baa yin nibe n’iseju mewa, e ma fun mi ni 5k ke de ma sanwo oti ti mo ti n mu lati eni.”

 

Esa bo l’enu Otunba bi ojo l’ojuese.

“Ose Kolamania. Sharp guy!!! Iwo y’ato s’awon gbantueyo, awon kokoro ewa. Iwo o ki n s’awon slow Suraju ti o ni liver ati gba ordinary nomba.”

 

Baba sare dide.

“Je n lo confamu information e boya bee lo ri. To ba le ri bee lasan, owo e di 10k ti n ba de, pelu gbogbo beer to ba fe.”

“Ko si wahala baba.”

 

Otunba ti duro ninu toilet bii iseju marun nigba teeyan kan kan’lekun. Kia lo si, Sade ti de.

 

“Se ibiyi safe sha?” ni ibeere to koko beere.

Sade dahun pelu ohun tutu.

“E ma f’oya sir. Mo ti gbe notice s’enu ona pe won n tu ibi yi se l’owo. Enikeni o le wole.

See Also

 

“Waaseere omo aiye, ori e pe.”

“E se sir. Saaju, mo fe kee mo pe mi o ki n se asewo o. Bi ore yin se s’oro lo wo mi leti.”

Otunba mi ori.

“Emi gaan mo be.”

“Iyen ikan, ki ni koko gan sir.”

 

Otunba dahun.

“Sade Sade. Ma worry, iwo saa se mi daada. Maa to ju e.”

“O daa o. Beyin Okunrin se ma n so niyen. O digba yen na ka to mo boya looto ni abi e kan n fumble lasan.”

 

Ka to wi ka to fo, Sade ba n’awo si sokoto Otunba. Wuye lo fa okun tu.

“E ka aso yin s’oke.”

Otunba ka dansiki e soke, o n w’oye nkan to fe sele.

 

Sade tu sokoto wale, o fa pata tele.

 

“Jeesu! Oko leleyi abi omo odo? Baba o! Jingosa re ke!

Otunba bu s’erin.

“Sade! Oko ni o, ki n se omo odo rara. Rora demo, mo mo pe ko tobi to bo se n ro yen.

 

Sade kunle siwaju Otunba, o fowo nu ori oko e bi eemeji. Ara Otunba se giri bi eni to te ina m’ole.

“Se ko si sir?”

“Rara o, owo e kan tutu ni.”

“Otunba yi papa. Owo tutu, e je ki n gbe s’enu tan kee to mo bo se n lo.”

 

Bi Sade se gbe oko otunba s’enu niyen o, to bere si pon la bii omode to n la sweet onigi. Lati ibi fila ori e lo sisale nibi koropon, omo yen nla oko yen bii kaa si nkan. Otunba na n mi loke loke bi pee o n sare gun oke aja. Bee l’oun naa fowo pa Sade lori. Nigba ti ise ka lara tan, o fa omu kan jade, o n tee bi eni te fere.

 

Laipe laijina, Otunba gbin kiin. Ato ba tu puupuu s’enu Sade.

 

[color-box]

Abiodun Awodele daily juggles the Lagos hustle with running his personal blog and trying to stay sane in an increasingly insane world. Prose (fiction) and poetry roll of his pen as the spirit directs and his first collection of short stories is expected to hit the shelves very soon. He blogs at www.versesbybeordoon.com. Follow him on twitter @MASKURAID

[/color-box]
View Comments (0)

Leave a Reply

Your email address will not be published.

© 2019 Mainland Book Cafe. All Rights Reserved.